Home 🎬 Bollywood 🎵 Pakistani 🎤 English Pop

Baba Mi Dimeji (Odu)

👤 Prince Gbenga Adeboye Funwontan 🎼 Stand up Comedy Extravaganza, Vol. 1 ⏱️ 7:41
🎵 647 characters
⏱️ 7:41 duration
🆔 ID: 9246172

📜 Lyrics

Hùn-ùn hún-ùn, ganbó ro bí mo tún yọ, mo tún yọ lónìí àlà funfun gbòò láàárín onírúurú aṣọ o
Ayé ò ní tapo s'álà náà Àràbà yìí ò ní wó, àmín (àmín)
Torí abẹ' rẹ' tútù ibẹ' n gbogbo ẹranko tí ń jẹun tí hán ti tún ń simi
Dictionary lèmi Àbẹ'fẹ' o ẹ bá ń fẹ' 'tumọ' rẹ' ẹ yẹ' mí wò fínnífínní ẹẹ' ri ń bẹ', ẹ kà mọ' kabìkan fabìkan ya o
Idà olójú méjì èdè, àní èkù ẹ' ni ẹ sábà mọ́-ọn gbá mú ẹ mọ'-ọn fi dojú t'ogun,
ẹni ó bá ní kí ní ọ' dán wò tí ń di'jú rẹ' mú, ọ' ń tẹluwáyà sí láká

⭐ Rate These Lyrics

Average: 0.0/5 • 0 ratings